Iyeoka Okoawo
Ìrísí
Iyeoka | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Iyeoka Ivie Okoawo |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹrin 1975 Boston, Massachusetts, United States |
Irú orin | Neo soul, R&B, soul, funk, hip hop |
Occupation(s) | Singer-songwriter, poet, educator |
Instruments | Vocals, tambourine |
Years active | 1996–present |
Labels | Underground Sun, Phanai Media Group |
Associated acts | The Rock By Funk Tribe |
Website | iyeoka.com |
Iyeoka Okoawo ( /iːˈjoʊkə/) (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1975) jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè America, akéwì (nípa ohun-ìní ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà) agbórinkalẹ̀, ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọ-nìyàn, olùkọ́ni àti ọmọ-ẹgbẹ́ TEDGlobal Fellow.[1] Irúfẹ́ àwọn orin tí ó máa ń kọ ni soul, R&B, rock, hip hop, àti jazz.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Fellows | Meet the TED Fellows | TEDGlobal 2010 Fellows". TED. Retrieved January 18, 2011.