Iyipada oju-ọjọ ni Amẹrika

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iwọn agbegbe ti imorusi: Awọn iwọn otutu apapọ ni gbogbo awọn agbegbe ni AMẸRIKA ti pọ si ni ọdun 120 sẹhin. [1]
Imurusi ni akoko diẹ: Awọn iwọn otutu ọdọọdun ti o kọja ni AMẸRIKA ti kọja aropin 1971–2000 fẹrẹẹ gbogbo ọdun ni ọrundun 21st.

Ìyípadà ojú-ọjọ́ ti yọrí sí ìgbọ́ná ní America pẹ̀lú 2.6 °F (1.4 °C) láti ọdún 1970. [2] Ojú-ọjọ́ ti America ń yípadà lọ́tà tó yàtọ̀ sí ti àwọn agbègbè rẹ̀.[3][4] Láti ọdún 2010 sí ọdún 2019 ni ìlú America ti ń ní àdojúkọ ìgbóná nínú ojú-ọjọ́.[5]

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú-ọjọ́ tó ga jù, àwọn ẹranko tó ti ń lọ sóko ìgbàgbé, àgbàrá òjò àti ìyuàngbẹ-ilẹ̀ ń pọ̀ si.[6][7][8] Àwọn ìyípadà tó ń dé bá ojú-ọjọ́ ń kó ipa ribiribi lórí àwọn ìjì-líle àti ìpele òkun tó ń ga si, ó sì tún ń kan àwọn agbègbè nínú ìlú.

Ní àpapọ̀, láti ọdún 1850, orílẹ̀-èdè America ti tú èéfín gáàsì tó pọ̀ jù lọ, ju gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tó ń lo gáàsì, tó sì ń ní ìyípadà tó ń dé bá ojú-ọjọ́ wọn.[9][10]

Eefin gaasi itujade[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  Àdàkọ:Excerpt

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help)  (Direct link to graphic; archive)
  2. Empty citation (help) 
  3. "Sixth Assessment Report". www.ipcc.ch. Retrieved 2021-08-20. 
  4. Heidari, Hadi; Arabi, Mazdak; Warziniack, Travis; Kao, Shih-Chieh (2020). "Assessing Shifts in Regional Hydroclimatic Conditions of U.S. River Basins in Response to Climate Change over the 21st Century" (in en). Earth's Future 8 (10): e2020EF001657. Bibcode 2020EaFut...801657H. doi:10.1029/2020EF001657. ISSN 2328-4277. https://agupubs.onlinelibrary.wiley.com/doi/abs/10.1029/2020EF001657. 
  5. US EPA, OAR (2016-06-27). "Climate Change Indicators: U.S. and Global Temperature". www.epa.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-20. 
  6. Heidari, Hadi; Arabi, Mazdak; Ghanbari, Mahshid; Warziniack, Travis (June 2020). "A Probabilistic Approach for Characterization of Sub-Annual Socioeconomic Drought Intensity-Duration-Frequency (IDF) Relationships in a Changing Environment" (in en). Water 12 (6): 1522. doi:10.3390/w12061522. 
  7. US EPA, OAR (2015-11-06). "Climate Change Indicators in the United States". www.epa.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29. 
  8. Casagr, Tina (2022-02-16). "Climate Change and Invasive Species - NISAW" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29. 
  9. US EPA, OAR (2016-06-27). "Climate Change Indicators: U.S. and Global Temperature". www.epa.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-20. 
  10. Empty citation (help)