Iṣan
Ìrísí
Iṣan | |
---|---|
A top-down view of skeletal muscle | |
Details | |
System | Musculoskeletal system |
Identifiers | |
Latin | musculus |
FMA | 5022 30316, 5022 |
Anatomical terminology |
Iṣan ni okùn ara tí ó rọ̀ jùlọ tí a lè rí ní ara púpọ̀ nínú ẹranko. Nínú iṣan kọ̀ọ̀kan ni a ti rí protein, actin àtimyosin tí wọ́n gba orín ara wọn kọjá nínú iṣan lọ́hùn ún, àwọn èròjà wọ̀nyí ni wọ́n ń jẹ́ kí iṣan le, rọ̀ tábí kí ó wà láàrin méjì gẹ́gẹ́ bí ipò tí ara bá wà lásìkò kan.
Iṣẹ́ iṣan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Láamra iṣẹ́ àwọn iṣan inù ara ni kí ó ràn wá lọ́wọ́ láti lè rìn, gbéra tàbí lọ láti ibìkan sí ibòmíràn lásìkò kan. Iṣan ló ma ń ṣiṣẹ́ ìbójútó ipò ara níbi ìdúró, ìbẹ̀rẹ̀, ìjókòó àti nínà sílẹ̀ gbalaja, tàbí nígbà tí a bá sùn sílẹ̀, iṣan ni ó ń ṣàkóso ìgbòkègbodò àti lílọ bíbọ̀ ara. Ó tún má ń jẹ́ kí àwọn bí ẹ̀jẹ̀ àti omi ó ríbi gbà káàkiri inú ara.[1] Skeletal muscles in turn can be divided into fast and slow twitch fibers.[2][3][4]
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Mackenzie, Colin (1918). The Action of Muscles: Including Muscle Rest and Muscle Re-education. England: Paul B. Hoeber. p. 1. https://books.google.com/books?id=lww9AAAAYAAJ. Retrieved 18 April 2015.
- ↑ Brainard, Jean; Gray-Wilson, Niamh; Harwood, Jessica; Karasov, Corliss; Kraus, Dors; Willan, Jane (2011). CK-12 Life Science Honors for Middle School. CK-12 Foundation. p. 451. https://books.google.com/books?id=52Y_O15i3C0C. Retrieved 18 April 2015.
- ↑ Alfred Carey Carpenter (2007). "Muscle". Anatomy Words. Retrieved 3 October 2012.
- ↑ Douglas Harper (2012). "Muscle". Online Etymology Dictionary. Retrieved 3 October 2012.