Jump to content

J'accuse...!

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
J'accuse

J'accuse (ìpè Faransé: ​[ʒakyz], "Mo fẹ̀sùn kan") jẹ́ leta igboro tó jẹ́ títê jáde ní January 13, 1898, nínú ìwê-ìròyìn L'Aurore láti ọwọ́ Olùkọ̀wé Émile Zola.