J ọkẹ́ Múyìwá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Jọkẹ́ Múyìwá jẹ́ òṣèré orí ìtàgé Yorùbá , àti ọ̀kan lára àwọn olùkò ilé-ẹ̀kọ́ Fásittì Ọlabisi Onabanjo ní ẹ̀ka eré orí-ìtàgé.[1] Ó gba àmì ẹ̀yẹ Òṣèré orí-ìtàgé tó peregedé jùlọ ní Nollywood, ẹlẹ́kaàrún irú rẹ̀ ( 5th Best of Nollywood Awards), fún ipa ribiribi rí ó kó nínú eré aládùn kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ayítalẹ̀, tí òṣèré Fẹ́mi Adébáyọ̀ darí rẹ̀.[2]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help) 

Àwọn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Joke Muyiwa on IMDb