Jackie Chan
Ìrísí
Jackie Chan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Can Gong saang 陳港生 7 Oṣù Kẹrin 1954 Hong Kong, C.H.I |
Iṣẹ́ | Actor, director, screenwriter, producer, vintner |
Ìgbà iṣẹ́ | 1962 – present |
Olólùfẹ́ | Lin Feng-Jiao (1982 - present) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Jackie Chan (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1954) jẹ́ òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọ̀kọrin ọmọ orílẹ̀ èdè China.[1]. Sinimá rẹ̀ máa ń dá lé ìjà afìpá àti gídígbò jà.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Blum, David (2009). "Hollywood actor". Hong Kong: 40–47.