Jump to content

Jacklord Jacobs

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Jacklord Bolaj Jacobs (ti a bi ni ọjọ kinni oṣu kinni ọdun 1970 ni ilu Benin ) je omo orile-ede Naijiria tele afẹṣẹja ti o dije lati ọdun 1994 si ọdun 2003. Gẹgẹbi akeko o ṣe aṣoju orile edè Naijiria ni Olimpiiki Igba ooru ọdun 1992 ni Ilu Barcelona, orilẹ-ede Spain . Ni ọdun kan lẹhinna o gba ami-ẹri fadaka ni 1993 World Amateur Boxing Championships ni Tampere, Finland, nibiti ti wọn ti lu ni ipari ìdíje ese jija na ( – 81 kg) ti Omo orilẹ-ede Kuba ti nje Ramón Garbey .

  • Oniyege Ami eri goolu ninu ere Gbogbo-Afirika ti 1991 ni Cairo gẹgẹbi iwuwo Imọlẹ, bori Paulo Maaselbe ti Tanzania ni ipari.
  • Jacobs ṣe aṣoju orilẹ-ede Naijiria gẹgẹbi afẹṣẹja ni ere Olimpiiki Ilu Barcelona 1992. Awọn abajade rẹ ni:
    • Ayika akokọ odabo
    • Padanu si owo Rostislav Zaulichniy (Iṣọkan Egbe) 8-16

Ni ọdun 1994 o ṣe akọse rẹ bi ọjọgbon

  • Boxing record for Jacklord Jacobs from BoxRec (registration required)