Jaiz Bank
Jaiz New Logo.jpg | |
Type | Private |
---|---|
Founded | 2003 |
Headquarters | Abuja, Nigeria |
Key people | Alhaji Umar Mutallab (Chairman), Dr. Sirajo Salisu (Managing Director & Chief Executive Officer)[1] |
Industry | Banking |
Products | Savings Account (Mudaraba),Current Account(Qard)Term Deposit Account, Sales Products,Leasing Products, Partnership Products (Financing) |
Revenue | ▼Aftertax:US$26.56 million (NGN:8.01 billion) (2018) |
Total assets | US$286.2 million (NGN:87.3 billion) (2018) |
Employees | 499 |
Website | jaizbankplc.com/ |
Jaiz Bank Plc, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn bánkìì tí ó ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ bánkìì ìsìlámù tí kò rọ̀gbọ̀kú lé ìjọba. Ó jẹ́ bánkíì àkọ́kọ́ fún ìdínwó ní orílé-èdè Nigeria tí olú ìyá ilé iṣẹ́ wọn wà ní Abuja, olú ìlú Nigeria.[2]
Ní December ọdún 2012, bánkíì yìí jẹ́ elétò ìsúná alábọ́dé ní Nigeria. Ní ìgbà yí, gbogbo owó inú àsùnwọ̀n wọn jẹ́ US$88.8 million (NGN:14.1 billion)[3] léyìí tí àwọn alága ìgbìmọ̀ máa ń pín owó tó tó US$63.6 million (NGN:10.1billion). Bánkìì yí ní ẹ̀ka ilé iṣẹ́ mẹ́ta dín lọ́ gbọ̀n. Tí wọ́n sì ní káàdi ATM àti èto Bánkìì ayélujára, ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀ alátẹ̀jíṣẹ́.[4]
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n dáa ṣílẹ̀ ní 2003, gẹ́gẹ́ bí JAIZ International Pls. Ní ọjọ́ kọkànlá November 2011, Jaiz gba ìwé eri
ẹ̀rí láti ọwọ́ Central Bánkìì ilẹ̀ Nàìjíríà. Láti máa sise gẹ́gẹ́ bí Bánkìì tí ó wà ní àrówótò. Ní ọjọ́ kẹfà January 2012, ilé ìṣe Bánkìì yí bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ilé ìṣe aladani JAIZ Bank pls ni ọ́fíìsì ní Abuja, Kaduna àti Kano.[5][6]
In 2013, Jaiz Bank tàn kálẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà, àti láàrin àwọn ìlú kéréje kéréje ilẹ̀ náà.[7] [8][9]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jaiz Bank Appoints Dr. Sirajo Salisu As Managing Director/CEO
- ↑ Anthony-Uko, N. S. E. (2012-07-05). "Nigeria: Jaiz Bank Seeks National Licence With N8 Billion Fresh Capital". Leadership (Abuja). http://allafrica.com/stories/201207050586.html.
- ↑ Lere, Mohammed (2013-12-20). "Nigeria: Jaiz Bank Records Operating Loss of N1.07 Billion in 2012 - Says Mutallab". Premium Times (Abuja). http://allafrica.com/stories/201312200277.html?viewall=1.
- ↑ "Jaiz Bank Plc: Private Company Information - Bloomberg". bloomberg.com. Retrieved 2018-03-09.
- ↑ History of Jaiz Bank Plc
- ↑ "The Origins of Jaiz Bank Plc". Archived from the original on 2012-06-24. Retrieved 2012-07-05. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Website of Jaiz Bank Plc". Archived from the original on 2012-06-24. Retrieved 2012-07-05. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Jaiz Bank secures licence to deliver Islamic banking". The Nation Newspaper. The Nation Newspaper. Retrieved 20 February 2019.
- ↑ "Jaiz Bank obtains national licence". Vanguard Newspaper. Vanguard Newspaper. Retrieved 20 February 2019.