James Adomian
Appearance
James Adomian (ọjọ́ ọ̀kànlélọ́gbọ̀n oṣù kínín ọdún 1980) jẹ́ aláwàdò àti òṣèré ará Amẹ́ríkà. Ó jẹ́ ìran Armenia.[1] Wọ́n mọ Adomian fún ọ̀pọ̀lọpò. eré ìtàgé tí ó ti ṣe bíi Vincent Price, Lewis Black, Orson Welles, Jesse Ventura, Paul Giamatti, Michael Caine, Philip Seymour Hoffman àti Comedy Bang! Bang!.[2]
Àwọn ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ The always funny & fresh to death James Adomian, 8 May 2013
- ↑ "James Adomian on Earwolf". Comedy Bang! Bang!. Archived from the original on 2013-09-18. Retrieved 2013-10-07.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: James Adomian |