James Carlisle

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

James Beethoven Carlisle, GCMG (ojoibi August 5, 1937) je Gomina Agba ile Antigua ati Barbuda tele. O je sisayan latowo Alakoso Agba igbana, Vere Cornwall Bird (to je omoolu akoko alakoso agba leyin ilominira latodo Britani) ni ojo 10 Osu Kefa, 1993 o si je yiyansipo latowo Ayaba ile Antigua titi di 30 Osu Kefa, 2007 - leyin odun 14.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]