Jump to content

James Coburn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
James Coburn (1972)

James Harrison Coburn III[1] ( /mz ˈkbɜːrnˌˈkbərn/; August 31, 1928 – November 18, 2002) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà. Ó ti kópa ní fíìmù tí ó ti ju àádọ́rin lọ, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ rẹ̀ jẹ́ eré tí ó gbóná, ó sì ti kópá ní bíi eré àgbéléwò bí ọgọ́rún.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]