Janet Egyir
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kàrún 1992 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Sekondi-Takoradi | ||
Ìga | 1.62m | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2010 – 2015 | Hasaacas Ladies F.C. | 86 | (16) |
2015 – 2017 | Víkingur Ólafsvík | 34 | (8) |
2018 – | Afturelding/Fram | 18 | (4) |
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Janet Egyir jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ keje, óṣu May ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere fun Afturelding/fram gẹgẹbi defender[1].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Janet kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[2].