Jump to content

Janet Yang

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Janet Yang
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Keje 1956 (1956-07-13) (ọmọ ọdún 68)
New York City, New York, U.S.
Iṣẹ́Producer/Entertainment and Media Consultant
Ìgbà iṣẹ́1985– títí di ìsinsìnyí
Àwọn ọmọ1

Janet Yang (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1956) jẹ́ olùṣe fíìmù àti ààrẹ Academy of Motion Picture Arts and Sciences lọ́wọ́ lọ́wọ́, Janet jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Yang àwọn eré Janet tí ó ti fi gba àmì ẹyẹ ni The Joy Luck Club, The People vs. Larry Flynt, Dark Matter, Indictment: The McMartin Trial, Zero Effect, Shanghai Calling, High Crimes, àti eré Over the Moon, èyí tí ó mú kí wọ́n yàn mọ́ ara àwọn tí ó tó sí àmì ẹyẹ Academy.

Ìpìlẹ̀ àti Èkó rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Janet Yang ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1956, ní ìlú Queens ti New York. Yang lọ ilé-ìwé Phillips Exeter Academy,[1] kí ó tó lọ sí Brown University, níbi tí ó ti gbájúmọ́ ìmò Chinese, lẹ́yìn náà tí ó sì gba àmì ẹyẹ MBAYunifásítì Kòlúmbíà.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Janet Yang '74 recalls Exeter's 'inclusive' environment". Phillips Exeter Academy (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-08-04. Retrieved 2022-08-10. 
  2. Hirahara, Naomi. Distinguished Asian American Business Leaders. Greenwood Publishing Group. pp. 219–221.