Jump to content

Janeth Shija

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Janeth Shija Simba jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó jẹ́ asọ́lé lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Simba Queens àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti Tanzania.[1][2]

Gbígbábọ́ọ̀lù fún orílẹ̀ èdè rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2019, Shija darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn obìnrin Tanzania tí ó wà lábẹ́ ogún ọdún fún ìdíje àkọ́kọ́ COSAFA U-20 Women's Championship ti ọdún 2019.[3] Ní ìparí ìdíje náà Tanzania jáwé olúborí lẹ́hìn tí ó na Zambia pẹ̀lú àwọ̀n méjì sí ẹyọ̀kan( 2-1) ní ìparí.[4]

Àwọn àmì ẹyẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • COSAFA U-20 Asiwaju Awọn Obirin : 2019
  • Asiwaju Awọn Obirin COSAFA : 2021

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Àdàkọ:GSA player
  2. Duret, Sebastien. "COSAFA Women's Cup - La TANZANIE remporte son premier titre". Footofeminin.fr : le football au féminin (in Èdè Faransé). Retrieved 2022-03-01. 
  3. "Twiga Stars news: Aisha Masaka and Irene Kisisa named in Cosafa U20 Women's Championship squad | Goal.com". www.goal.com. Retrieved 2022-03-02. 
  4. "Botswana, Zambia draw, meet in semis – Zambia Daily Mail". www.daily-mail.co.zm. Retrieved 2022-03-02.