Jump to content

Jean Tarcisius Batamboc

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Jean Tarcisius Batamboc (ti a bi ni ọjọ kinni oṣu kewa ọdun 1987) elere ije orilẹ-ede Cameroon ti oun sa 100 mita.

O dije ninu ìdíje 2011 All-Africa Games, 2012 African Championships, 2014 African Championships ati 2015 African Games lai k'ogo ja ipele ipalemo. O tun didje ni 2017 World Championships, ti o fi wa ni ikehin ni ipalemo ìdíje naa.

Gẹgẹbi ara ti ẹgbẹ agbapada mita 4 × 100 ti orilẹ-ede Kamẹru, o pari ni ipo kaarun ninu idije Afirika 2012 ati ipo kẹfa ni idije Afirika 2014 . [1]