Jump to content

Jeffrey Dean Morgan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jeffrey Dean Morgan
Morgan ní 2019 San Diego Comic-Con
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kẹrin 1966 (1966-04-22) (ọmọ ọdún 58)
Seattle, Washington, U.S.
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1991–present
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ2

Jeffrey Dean Morgan (tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin ọdún 1966[1]) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Negan nínú fíìmù AMC horror drama tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Walking Dead (2016–2022), àti nínú The Walking Dead: Dead City (2023-present), ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ oríyìn fún ipa rẹ̀ nínú eré yìí. Àwọn eré míràn tí ó ti farahàn ni gẹ́gẹ́ bi John Winchester ní eré the CW tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Supernatural (2005–2007; 2019), gẹ́gẹ́ bi Denny Duquette nínú eré ABC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Grey's Anatomy (2006–2009), gẹ́gẹ́ bi Jason Crouse nínú eré CBS tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ gẹ́gẹ́ bi The Good Wife (2015–2016), aláwadà nínú Watchmen (2009), àti nínú àwọn eré bi P.S I Love You (2007), The Losers (2010), Red Dawn (2012),àti Rampage (2018).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Boland, Yasmin (August 16, 2021). "Horoscope". TV Guide: p. 72.