Elena Dementieva
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Jelena Dementieva)
Orílẹ̀-èdè | Rọ́síà |
---|---|
Ibùgbé | Monte Carlo, Monaco |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹ̀wá 1981 Moscow, Russian SFSR, Soviet Union |
Ìga | 1.80 m (5 ft 11 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 25 August 1998 |
Ìgbà tó fẹ̀yìntì | 29 October 2010 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | US$ 14,867,437 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 576–273 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 16 WTA, 3 ITF titles |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 3 (6 April 2009) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | SF (2009) |
Open Fránsì | F (2004) |
Wimbledon | SF (2008, 2009) |
Open Amẹ́ríkà | F (2004) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje WTA | SF (2000, 2008) |
Ìdíje Òlímpíkì | Gold medal (2008) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 152–86 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 6 WTA, 3 ITF titles |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 5 (14 April 2003) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | 3R (2005, 2006, 2007) |
Open Fránsì | 3R (2004) |
Wimbledon | SF (2003) |
Open Amẹ́ríkà | F (2002, 2005) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje WTA | W (2002) |
Ìdíje Òlímpíkì | 1R (2004) |
Last updated on: 25 October 2010. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Women's tennis | |||
---|---|---|---|
Adíje fún Rọ́síà | |||
Wúrà | 2008 Beijing | Singles | |
Fàdákà | 2000 Sydney | Singles |
Elena Viatcheslavovna Dementieva (Rọ́síà: Елена Вячеславовна Дементьева, Pípè ní èdè Rọ́síà: [jɪˈlʲenə dʲɪˈmʲentʲjɪvə]; ọjọ́ìbí 15 October 1981) ni oníṣẹ́ agbá tẹ́nísì ará Rọ́síà tó ti fẹ̀yìntì.[1] Dementieva gbajúmọ̀ fún àṣeyọrí rẹ̀ nínú ìdíje ni Òlímpíkì 2008 ní Beijing nígbà tó gba ẹ̀sọ́ wúrà ìdíje àwọn obìnrin ẹnìkan, lẹ́yìn ìgbà tó gba ẹ̀sọ́ fàdákà níbi ìdíje Òlímpíkì ọdún 2000 ní Sydney. Ó gba ife-ẹ̀yẹ ìdíje àwọn ẹnìkan 16 lórí WTA, ó dé òpin àwọn ìdíje Open Fíránsì ọdún 2004 àti Open Amẹ́ríkà ọdún 2004.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Retirement of Elena Dementieva". wtatour.com. 29 October 2010. Retrieved 30 October 2010.