Jessica Nkosi
Ìrísí
Jessica Nkosi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Jessica Ayanda Nkosi 20 Oṣù Kínní 1990 Empangeni, KwaZulu-Natal, South Africa |
Iṣẹ́ | Actress Presenter |
Ìgbà iṣẹ́ | 2013 - Present |
Àwọn ọmọ | 1 |
Jessica Ayanda Nkosi (bíi ni ọjọ́ ogún oṣù kìíní ọdún 1990) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Jessica sì ìlú Empangeni. Ní ìgbà tí ó pè ọmọ ọdún mọ́kànlá, bàbà rẹ di aláìsí.[2] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of KwasZulu-Natal, ó sì gboyè nínú eré ṣíṣe ni ọdún 2012.[3]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2013, Nkosi bẹ̀rẹ̀ ère ṣíṣe, ó kó ipa Qondisile nínú eré Isibaya, [4]eré náà sì lọ jẹ́ kó di gbajúmọ̀. Ní ọdún 2017, ó ṣe Eve nínú eré Ayeye. Ní ọdún 2017, ó ṣe atọkun fún ètò A-List èyí tí BET gbé kalẹ̀.[5] Ó ṣe atọkun fún ètò Our Perfect Wedding[6]. Ó jẹ́ àmbásádọ̀ fun ilé iṣẹ́ Duran Tourism,[7] Clinique[8] àti Volvo[9].
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Jessica Nkosi Biography: Isibaya Exit, Tips On Hygiene, Age, Boyfriend, Marriage, Baby, Controversy, Dresses, House - Updated, 9th April 2020". ZAlebs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-11-17. Retrieved 2020-04-20.
- ↑ Nkosi, Joseph (2020-03-14). "Jessica Nkosi age, biography, baby, qualifications, boyfriend & baby". The Nation SA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-20.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Jessica Nkosi – University of KwaZulu-Natal". www.ukzn.ac.za. Archived from the original on 2020-08-07. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ "Jessica Nkosi". Mzansi Magic - Jessica Nkosi (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-21.
- ↑ "Authentic, witty and fun – BET A-list brings out the best in Jessica Nkosi". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-30. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ "Our Perfect Wedding: Jessica Nkosi joins us!". Mzansi Magic - Our Perfect Wedding: Jessica Nkosi joins us! (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-19. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ "Tourism marketing drive launched". Zululand Observer. 2014-10-02. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ QuenchSA (2016-07-11). "Jessica Nkosi Unveiled As New Clinique Brand Ambassador!". QuenchSA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-08-14. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ Mathebula, Kwanele (2019-04-09). "Jessica Nkosi is the new ambassador for Volvo!". Bona Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-08-08. Retrieved 2020-04-21.