Jump to content

Jim Fouché

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jacobus Johannes Fouché

Jacobus Johannes Fouché in 1968
2nd State President of South Africa
In office
10 April 1968 – 9 April 1975
Alákóso ÀgbàJohannes Vorster
AsíwájúCharles Robberts Swart
Tom Naudé (acting)
Arọ́pòJan de Klerk (acting)
Nicolaas Diederichs
Minister of Agricultural Technical Services and Water Affairs
In office
1966–1968
Alákóso ÀgbàHendrik Verwoerd
AsíwájúPieter Kruger Le Roux
Arọ́pòDirk Cornelius Uys
Minister of Defence
In office
14 December 1959 – 1 April 1966
Alákóso ÀgbàHendrik Verwoerd
Johannes Vorster
AsíwájúFrans Erasmus
Arọ́pòPieter Willem Botha
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1898-06-06)6 Oṣù Kẹfà 1898
Wepener, Orange Free State (now Free State, South Africa)
Aláìsí23 September 1980(1980-09-23) (ọmọ ọdún 82)
Cape Town, Cape Province, South Africa
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational
(Àwọn) olólùfẹ́
Letta McDonald (m. 1920)
Àwọn ọmọ2
Nickname(s)Jim

Jacobus Johannes "Jim" Fouché, (6 June 1898 – 23 September 1980[1]), tí àwọn mìíràn mọ̀ sí J. J. Fouché, jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè South Africa. Òun ni ààrẹ orílẹ̀ èdè South Africa láàrin ọdún 1968 sí 1975.

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Jacobus ní Boer republic ti Orange Free State ní ọdún 1898, ilé ìwé tí ó lọ ṣì ni Paarl Boys' High School.[2] Ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Victoria College, Stellenbosch àti ní Stellenbosch University ní ọdún 1966.[2]

Fouché jẹ́ àgbẹ̀ àti ọmọ ẹgbẹ́ National Party fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, a yàn án gẹ́gẹ́ bi aṣojú Smithfield ní House of Assembly orílẹ̀ èdè South Africa láti ọdún 1941 sí 1950, àti gẹ́gẹ́ bi aṣojú Bloemfontein West láàrin ọdún 1960 àti 1968.[2]

Fouché jẹ́ adar Orange Free State láti ọdún 1950 sí 1959, kí ó tó di Minister of Defence ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù Kejìlá ọdún 1959, ó di ipò yìí mú títí di ọjọ́ Kínní oṣù kẹrin ọdún 1966[3] àti Mínísítà fún ètò ọ̀gbìn àti omi láàrin ọdún 1966 sí 1968.[2] A yàn án gẹ́gẹ́ bi ààre láti rọ́pò Ebenhaezer Dönges (ẹni tí a yàn gẹ́gẹ́ bí ààre ṣùgbọ́n ó fi ayé sílẹ̀ kí ó tó dórí oyẹ̀).[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Jacobus Johannes Fouché. archontology.org
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 The international year book and statesmen's who's who. 1979 (27th ed.). East Grinstead: Kelly's Directories. 1979. pp. 246. ISBN 978-0-610-00520-6. http://archive.org/details/internationalyea0000unse_r1z4. 
  3. C.J. Nöthling, E.M. Meyers (1982). "Leaders through the years (1912–1982)". Scientaria Militaria 12 (2): 92. http://scientiamilitaria.journals.ac.za/pub/article/view/631.