Jump to content

Jo Yoon-hee

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jo Yoon-hee
Jo Yoon-hee in 2019
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹ̀wá 1982 (1982-10-13) (ọmọ ọdún 42)
Cheongju, Chungcheongbuk-do, South Korea[1]
Orúkọ mírànCho Yoon-hee
Ẹ̀kọ́Dongduk Women's University - Broadcasting and Entertainment
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1999–present
AgentKing Kong by Starship
Olólùfẹ́
Lee Dong-gun
(m. 2017; div. 2020)
Àwọn ọmọ1
Jo Yoon-hee
Hangul조윤희
Revised RomanizationJo Yun-hui
McCune–ReischauerCho Yunhŭi

Jo Yoon-hee (tí a bí ní October 13, 1982) jẹ́ òṣèré South Korea kan. Ó jẹ́ olókìkí jùlọ fún kikopa nínú àwọn television dramas My Husband got a Family (2012) àti Nine (2013). [2]

Ìgbésí ayé ara ẹni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó wá láti cheongju, Chungcheongbuk-do, ṣùgbọ́n ó kó lọ sí Seoul, olú ìlú South Korea nígbà tí ó di ọmọ ọdún márùn-ún, ó sì ti ń gbé níbẹ̀ láti ìgbà yẹn.

Ní oṣù karùn-ún ọjọ́ Kejì ọdún 2017, Jo kédè pé ó ti ṣe àkọsílẹ̀ ìgbéyàwó rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀ṣère Lee Dong-un tó ṣeré nínú fíìmù "The Gentlemen of Wolgyesu Tailor", wọ́n sì tún retí ọmọ àkọ́kọ́ wọn. Tọkọtaya sì ṣe ayẹyẹ ìgbéyàwó bòókẹ́lẹ́ ní oṣù kẹsàn-án Ọjọ́ kọ́kàndínlọ́gbọ̀n, wn sì bí ọmọbìnrin tuntun ní oṣù Kejìlá ọjọ́ kẹ́rìnlá, ní ọdún 2017.

Ní oṣù karùn-ún ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n 28, Ọdún 2020, a ròyìn pé àwọn òṣèré méjì ti kọ́ ara wọn sílẹ. Wọ́n pínyà látàrí àwọn àìjọra wọn, tí kò níyànjú. Gẹ́gẹ́bí ìròyìn kan láti "dispatch" Jo gba àgbàtọ́ ọ̀dọ́mọbìnrin wọn.

  1. "조윤희". Marie Claire Korea (in Èdè Kòríà). 2023-01-04. 
  2. Empty citation (help)