Jump to content

Joana Foster

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joana Foster
Ọjọ́ìbí(1946-02-15)15 Oṣù Kejì 1946
Aláìsí5 November 2016(2016-11-05) (ọmọ ọdún 70)
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Ọmọ orílẹ̀-èdè
Iṣẹ́Lawyer, Women's rights activist
MovementFeminism, Nuclear disarmament[1]
Board member ofAWDF, WILDAF
Olólùfẹ́Michael Foster
ẸbíRichard Wilkinson and Helen Wilkinson

Joana Foster (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kejì ọdún 1946, tí ó sì kú ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kọkànlá ọdún 2016) jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn ti orílẹ̀-èdè Ghana tó sì tún tan mọ́ orílẹ̀-èdè Britain. Iṣẹ́ agbẹjọ́rò ni arábìnrin yìí yàn láàyò.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìlú Ghana ní wọ́n bí Joana sí, ilé-ìwé Achimota School ni ó lọ.[3]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iṣẹ́ agbẹjọ́rò ni Joana yàn láàyò.

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Joana ṣe ìdásílẹ̀ African Women's Development Fund pẹ̀lú Bisi Adeleye-Fayemi àti Hilda M. Tadria ní ọdún 2000.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "WHRD Tribute". AWID Women's Right. AWID Women's Right. Retrieved 6 May 2017. 
  2. "LOUD WHISPERS: Joana Silochina Foster (1946-2016)". Above Whispers. Above Whispers. Retrieved 4 March 2017. 
  3. Sekyiamah, Nana Darkoa. "Joana Foster: 'She made African women realise they can do anything'". The Guardian. The Guardian. Retrieved 6 May 2017. 
  4. "Joana Foster: 'She made African women realise they can do anything'". The Guardian. Guardian. Retrieved 4 March 2017.