Joaquim Rafael Branco
Appearance
Joaquim Rafael Branco | |
---|---|
Prime Minister of São Tomé and Príncipe | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 22 June 2008 | |
Ààrẹ | Fradique de Menezes |
Asíwájú | Patrice Trovoada |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1953 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | MLSTP-PSD |
Joaquim Rafael Branco (ojoibi 1953) je oloselu ara orile-ede São Tomé ati Prinsipe. O hun ni Aare egbe oloselu Movement for the Liberation of São Tomé and Príncipe/Social Democratic Party (MLSTP/PSD), ati Alakoso Agba orile-ede ohun lowolowo.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Líder da oposição em São Tomé Príncipe designado primeiro-ministro", Panapress, June 12, 2008 (Potogí).