Jump to content

Johann Rupert

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Johann Rupert
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹfà 1950 (1950-06-01) (ọmọ ọdún 74)
Stellenbosch, Cape Province, Union of South Africa
Iléẹ̀kọ́ gígaStellenbosch University
Iṣẹ́Chairman of Compagnie Financiere Richemont SA[1]
Gbajúmọ̀ fúnLuxury goods
Olólùfẹ́Gaynor Rupert
Àwọn ọmọ3
Parent(s)Anton and Huberte Rupert

Johann Peter Rupert (tí a bí ní ọjọ́ Kínní oṣù kẹfà ọdún 1950) jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ ède South Africa, òun ni ọmọkùnrin Anton Rupert àti Huberte. Òun ni alága ilé isẹ́ Remgro ní South Africa. Láti oṣù kẹrin ọdún 2010 ni ó ti jẹ́ CEO ilé iṣẹ́ Compagnie Financiere Richemont. Rupert àti ìdílé rẹ̀ ni Forbes sọ pé ó lówó julọ ní South Africa ní ọdún 2024, pẹ̀lú owó àti ìkan ìní tí ó tó US$12.0 billion.[2]

Rupert dàgbà ní Stellenbosch, ní ibi tí ó ti lọ ilé ìwé Paul Roos Gymnasium àti Yunifásítì Stellenbosch, láti kó nípa economics àti company law. Ó fi ilé ìwé náà kalẹ̀ láti bẹ̀rẹ̀ isẹ́ òwò, síbẹ̀ síbẹ̀, ní ọdún 2004, Yunifásítì Stellenbosch fún ní honorary doctorate ní Economics.[3]

Ní ọdún 2008, Yunifásítì Nelson Mandela Metropolitan fun ní àmì ẹyẹ doctorate mìíràn.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Johann Rupert & family". Forbes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-08-07. 
  2. "Johann Rupert & family". Forbes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-09-27. 
  3. "Chancellor". sun.ac.za. Retrieved 13 October 2015. 
  4. "Synchronised Speakers | Johann Rupert". synchronisedspeakers.co.za. Archived from the original on 3 September 2018. Retrieved 13 October 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)