Johannes Heesters

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Johannes Heesters
Johannes Heesters.jpg
Heesters in March 2006
Born Oṣù Kejìlá 5, 1903 (1903-12-05) (ọmọ ọdún 113)
Amersfoort, Netherlands
Years active 1917–present
Net worth $65,000,000
Spouse(s) Simone Rethel (1991)
Website
www.johannes-heesters.de
Notes
Won 19 Bambi-awards

Johannes Heesters (ojoibi December 5, 1903) je osere, akorin, ati onifaaji ara Hollandi .


O ti sise fun odun 91, be sini o sise nibi ti won ti unso ede Jemani. Titi to fi di April 2011, Heesters ni eni agbalagba julo to un sise ninu faaji. Awon kan ko bi fe feran Heesters nitoripe o korin fun Adolf Hitler nigba kan ri.[1] Heesters segbeyawo ni emaji: lati 1930-1985 o fe osere ara Belgiom Louise Ghijs (1906) ati lati 1991-doni o fe Simone Rethel. Heesters ni omobinrin meji latodo iyawo re akoko ati awon omoomo marun, omoomo-unla mokanla, omoomo-unla-unla medogbon ati omoomokunrin-unla-unla-unla kan ni titi 2011.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon Ibiitakun[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]