John Couch Adams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
John Couch Adams

Ìbí 15 Oṣù Kẹfà, 1819(1819-06-15)
Laneast, Launceston, Cornwall
Aláìsí 21 Oṣù Kínní, 1892 (ọmọ ọdún 72)
Cambridge Observatory, Cambridgeshire, England
Ọmọ orílẹ̀-èdè British
Ẹ̀yà British
Ibi ẹ̀kọ́ University of Cambridge
Academic advisors John Hymers

John Couch Adams

Wón bí Adams ní 1819. Ó kú ní 1892. Omo ilè Gèésì ni. Onímò ìsirò (Mathematics) ni. Astronomer sì ni pèlú. Òun àti Leverrier, astronomer omo ilè Faransé kan ni wón jo gba ogo síse àwárí Neptune ní 1846. Òtòòtò ni wón se isé tí wón gba ògo rè yìí.