John Madaki
Ìrísí
John Yahaya Madaki | |
---|---|
Governor of Katsina State | |
In office December 1989 – 2 January 1992 | |
Asíwájú | Lawrence Onoja |
Arọ́pò | Saidu Barda |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Gurara LGA, Niger State, Nigeria |
Aláìsí | 8 January 2018 |
John Madaki jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina nígbà kan rí. A yàn án sípò ní oṣù Kejìlá ọdún 1989 lásìkò ìjọba ológun tí Ààrẹ Ibrahim Babangida. Saidu Barda ló jẹ́ lẹ́yìn rẹ̀ lásìkò ìjọba alágbádá ni oṣù kìíní ọdún 1992.[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ globalsentinel (2018-01-10). "Niger State mourns Colonel John Madaki rtd". Global Sentinel. Archived from the original on 2019-12-26. Retrieved 2019-12-26.
- ↑ "John Madaki (1947-2018) – a tribute". The Sun Nigeria. 2018-02-01. Retrieved 2019-12-26.