John O. Agwunobi
Ìrísí
John Agwunobi | |
---|---|
Assistant Secretary for Health | |
In office January 4, 2006 – September 4, 2007 | |
Ààrẹ | George W. Bush |
Asíwájú | Cristina Beato (Acting) |
Arọ́pò | Joxel García |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Dundee, Scotland, UK |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Republican |
Relatives | Andrew Agwunobi (brother) |
Education | University of Jos (BS, MD) Johns Hopkins University (MPH) Georgetown University (MBA) |
Military service | |
Allegiance | United States |
Branch/service | U.S. Public Health Service |
Years of service | 2006–2007 |
Rank | Admiral |
Commands | United States Public Health Service |
Awards | Public Health Service Regular Corps Ribbon |
John O. Agwunobi jẹ́ ọmọ Scotland, tó sì tún tan mọ́ orílẹl-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ oníṣègùn àwọn ọmọdé, ó sì fìgbà kan jẹ́ adarí agbà àti alága Herbalife Nutrition.[1] Òun sì ni igbákejì ààrẹ ti Walmart, àti ààrẹ retailer health and wellness business láti ọdún 2007 wọ 2014.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Admiral John O. Agwunobi". georgewbush-whitehouse.archives.gov. Retrieved 2020-05-27.
- ↑ "Dr. John Agwunobi to join Wal-Mart as Senior Vice President and President for the Professional Services Division". news.walmart.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-07-18. Retrieved 2017-12-22.