Johnson Suleman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Johnson Suleman
Suleman in 2012
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Pastor, televangelist
Websiteapostlejohnsonsuleman.com

Johnson Suleman tí a tún mò sí Aposteli Johnson Suleman(tí a bí ní March 24, 1971 [1] ) jé omo bibi ìpínlè Edo, a bi sí ìlú Beninìpínlè edo, Nàìjirià. A bi sínú idile tí musulumi, léyìn ojó díè tí a bi, awon woli wà si Benin(ìlú tí a bi sí) láti wá so fun òbí rè pé a ti bi omo tí yó je Woli niwaju Oluwa [2]. Aposteli Johnson Suleman lo ilé-èkó akobere àti secondary ní ìlú Auchi [3], ìpínlè Edo. Aposteli Johnson dá ìjo Omega fire ministry kalè ní odun 2004 [4]. Apostle Johnson Suleman fé Lizzy Johnson Suleiman ní odun 2004 [5], tokotoya náà sì bí omo marun [6]

Àwon ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Joe, Ibeh C; Joe, Ibeh C; Joe, Ibeh C (2021-08-23). "Apostle Johnson Suleman – Biography, Age, Wife, Family, Net Worth, Career, & More". The Preachers' Portal (in Èdè Sípáníìṣì). Retrieved 2022-03-03. 
  2. "Apostle Johnson Suleman, Pastor, Prophet, Evangelist, Nigeria Personality Profiles". Nigeriagalleria. 1994-06-20. Retrieved 2022-03-03. 
  3. Africa, Information Guide (1971-03-24). "Apostle Johnson Suleman Biography, Age, Early Life, Family, Education, Career And Net Worth ~ Information Guide Africa". Information Guide Africa. Retrieved 2022-03-03. 
  4. Stets, Regina (2018-01-17). "Facts you should about Apostle Johnson Suleman and his prophecies for 2017 and 2018". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2022-03-03. 
  5. "Meet Apostle Johnson Suleman’s Wife and The Children They Share". AnswersAfrica.com. 2021-10-12. Retrieved 2022-03-03. 
  6. "Apostle Johnson Suleman Children (Photos)". Insidegistblog. 2021-09-08. Archived from the original on 2022-03-03. Retrieved 2022-03-03.