Joplin
Ìrísí
Joplin, Missouri | |
---|---|
Ìlú | |
Aerial view of downtown Joplin, 2009 | |
Motto(s): "Proud of Our Past...Shaping Our Future'" | |
ibudo ni ipinle Missouri | |
Ibile | Orile-ede Amerika |
Ipinle | Missouri |
Àwọn ibile | Jasper, Newton |
Incorporated | 1873 |
Government | |
• Mayor | Melodee Colbert-Kean |
Area | |
• Total | Àdàkọ:Infobox settlement/metric/mag |
• Land | 81.4 km2 (31.4 sq mi) |
• Water | 0.2 km2 (0.1 sq mi) |
Elevation | 306 m (1,004 ft) |
Population | |
• Total | 50,150 |
• Density | 610/km2 (1,600/sq mi) |
Time zone | UTC-6 (CST) |
• Summer (DST) | UTC-5 (CDT) |
ZIP codes | 64801-64804 |
Area code(s) | 417 |
FIPS code | 29-37592[2] |
GNIS feature ID | 0729911[3] |
Website | JoplinMO.org |
Joplin jẹ́ ilù kàn ní apá gúúsù Ibile Jasper àti apá áríwa Ibile Newton ní apá gúúsù iwọ
oòrùn ìpínlẹ̀ Missouri ní orílè èdè Amerika. Joplin ní ìlú tí ó tóbì jù lọ Ìbílẹ̀ Jasper bó tilẹ̀ jẹ́ pé kíì ṣe ibùjókòó ìjọba ìbílẹ̀. Títí ìgbà ìkànìyàn 2010, ìlú náà ní àlábùgbè tótó 50,150.[1] Ní 2010, àgbègbè tó yíká Metropolitan Statistical Area ní àlábùgbè tótó 175,518.[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "2010 City Population and Housing Occupancy Status". U.S. Census Bureau. Retrieved May 23, 2011.
- ↑ "American FactFinder". United States Census Bureau. Retrieved 2008-01-31.
- ↑ "US Board on Geographic Names". United States Geological Survey. 2007-10-25. Retrieved 2008-01-31.
- ↑ "Joplin, MO MSA Population and Components of Change". Recenter.tamu.edu. Archived from the original on July 30, 2010. Retrieved May 24, 2011.