Joseph Addison
Appearance
Joseph Addison je olukowe omo Ile Geesi Wón bí Addison ní 1672. Ó kú ní 1719. Ònkòwé ni Addison olósèlú sì ni pèlú. Ó kópa nínú ‘Taller’ òun àti Steele ni wón sì jo dá ‘Spectator’ sílè.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |