Joseph H. Greenberg

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Joseph Greenberg
Ìbí May 28, 1915 (1915-05-28)
Brooklyn, New York
Aláìsí May 7, 2001 (2001-05-08)
Stanford, California
Ọmọ orílẹ̀-èdè American
Pápá linguistics, African anthropology
Ilé-ẹ̀kọ́ Columbia University
Stanford University
Ó gbajúmọ̀ fún work in linguistic typology, genetic classification of languages
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí Haile Selassie I Prize for African Research (1967), Talcott Parsons Prize for Social Science (1997)

Ohun tí ònkòwé sisé lé lórí nínú ìwé yìí ìpín èdè Aáfíríkà sí ebí. Orí méje ni ìwé náà ní. Orí kìíní ni ó sòrò nípa ìlàlà tí a lè tèlé láti pín èdè kan sí ebí. Léyìn èyí ni ònkòwé wá bèrè sí ní í se àlàyé àwon ebí tí ó pín èdè Aáfíríkà sí. Orí keyì sòrò nípa Niger-Cong; èkéta, Afrocasiatic; èkérin; Khoisan; èkárùn-ún, Chari-Nile; èkéfà; Nilo-Saharan nígbà tí orí kéje sòrò nípa Niger-Kordofania. Yàtò sí orí méje yìí, ìwé náà ní index to language classification, key to language classification àti index of languages. Òpòlopò máàpù ni ònkòwé yà sínú ìwé yìí. Ní ìparí, ònkòwé se àfikún díè sí ìwé yìí ó sì se àtúnse àwon àsìse tí ó se àkíyèsí nínú ìwé náà. Bí àwon ohun tí ó wa nínú ìwé náà se lo ní olóríjorí nì yí:

Iwe ti a yewo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Joseph H. Greenberg (1966), The Languages of Arica. Bloomingtion; Indian University Press.