Josephine Hull

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Josephine Hull
Hull in the Harvey trailer, 1950
Ọjọ́ìbíMary Josephine Sherwood
(1877-01-03)Oṣù Kínní 3, 1877
Newtonville, Massachusetts, U.S.
AláìsíMarch 12, 1957(1957-03-12) (ọmọ ọdún 80)
The Bronx, New York City, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaRadcliffe College
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1905–1955
Olólùfẹ́
Shelly Hull
(m. 1910; died 1919)

Marie Josephine Hull (née Sherwood; tí a bí ní oṣù kìíní, ọjọ́ kẹta, ọdún 1877 sí oṣù kẹta ọjọ́ kejìlá, ọdún 1957) jẹ́ onítàgé ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti òṣèré obìnrin fíìmù tí ó sì jẹ́ ìtọsọ́nà àwọn eré. Ó ní àṣeyọrí àádọ́ta ọdún lórí ìtàgé nígbà tí ó ń gbé àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tó ti gba ìdánimọ̀ lọ inú fíìmù. Ó gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ fún òṣèré àtìlẹ́yìn obìnrin tó dára jùlọ fún eré "Harvey" (ọdún 1950), apá iṣẹ́ tí wọ́n sábà máa ń ṣe lórí ìtàgé Broadway. Ní ìgbà mìíràn, wọ́n máa ń pè é ní Josephine Sherwood.[1]

Ìtàn Ìgbésí Ayé Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Hull ní oṣù kìíní ọjọ́ kẹta, ọdún 1877,[2] ní Newtonville, Massachusetts, ìkan nínú àwọn ọmọ mẹ́rin tí a bí sí William H. Sherwood àti Mary Elizabeth "Minnie" Tewkesbury,[3] àmọ́ ó máa wá yọ kúrò nínú ọjọ́ orí rẹ̀.[4] Ó lọ sí Ilé-ìwé ìkọrin New England Conservatory of Music àti kọlẹẹjì Radcliffe, tí àwọn méjèèjì jọ wà ní sàkání Boston.

Àwọn Ìtọ́ka Sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Josephine Hull". Internet Broadway Database. Retrieved July 21, 2020. 
  2. 1880 United States Census (Massachusetts, Middlesex, Newton Ward 2, District 474, page 55); 1900 United States Census (Massachusetts, Middlesex, Newton Ward 2, District 895, page 19), each showing Mary Josephine Sherwood born to William Sherwood and Mary E. Tewksbury Sherwood in Massachusetts in January 1877.
  3. Great Stars of the American Stage by Daniel Blum ca. 1952 Profile #111
  4. For example, her marriage certificate in 1910 (when she was 33) states that she was 28. See Marriage Records, Chicago, Illinois and Newton, Massachusetts, April 3, 1910, (Mary Josephine Sherwood and Shelly Vaughn Hull). She likewise represented herself as several years younger in the 1910 census. 1910 United States Census (Connecticut, Litchfield, Barkhamstead, District 249, page 21), stating that "Josephine Hull" was 27. Still later sources list Hull as born on January 3, 1886, nine years later than her real birth date.