Josh2Funny

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chibuike Josh Alfred tí gbogbo ayé mọ̀ sí Josh2Funny jẹ́ adẹ́rìn-ín-pòṣónú, òsèré àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3]

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Josh2Funny ní Ìpínlẹ̀ Anámbra, ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá, ọdún 1990.

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Lagos Real Fake Life[4] (2018)
  • Money Miss Road[5] (2022)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Nwankwọ, Izuu (2021). "8 Eyes on the future". Yabbing and Wording: The Artistry of Nigerian Stand-up Comedy. NISC (Pty) Ltd. pp. 155–156. doi:10.2307/j.ctv2gvdmcb.14. JSTOR j.ctv2gvdmcb. 
  2. Fajana, Adekunle (19 January 2022). "Comedian Josh2Funny undergoes surgery after suffering 11-year illness". Ripples Nigeria. Retrieved 30 July 2022. 
  3. Salaudeen, Aisha (27 June 2020). "This Nigerian comic is getting a lot of love on TikTok with the 'Don't Leave Me' challenge". CNN. Lagos, Nigeria. Retrieved 30 July 2022. 
  4. Awa, Omiko (18 November 2018). "Lagos Real Fake Life exposes other seamy side of city". The Guardian. Retrieved 30 July 2022. 
  5. Daniel, Eniola (23 July 2022). "Charly Boy, Swanky JKA, Josh2funny in Money Miss Road". The Guardian. Retrieved 30 July 2022.