Joshua Selman
Joshua Selman Nimmak tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Aposteli Jóṣúà Selman tàbí AJS jẹ́ ojisẹ Ọlọrun, elero orin àti onímọ̀-ẹ̀rọ Kemikali ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Òun ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti adarí ìjọ Eternity Network International(ẸNI), ó sì ma ún dárí ìsìn kan tí àpèlé rẹ̀ Koinonia. Joshua Selman jẹ́ omobibi ìpínlè Plateau.[1]
Ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Joshua Selman ní ọjọ́ karundinlogbon oṣù kẹfà ọdún 1980 ní Jos, orílè-èdè Nàìjíríà[2]. Ilé krisitiani ni wọ́n bi sí. Ó kékọ̀ọ́ gboyè nípa imọ-ẹrọ kemikali ni Ile-ẹkọ gíga tí Ahmadu Bello ni zaria, ní ìlú Kaduna ni Nàìjíríà.[3]
Ìṣe ìránṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Selman béèrè ìṣe ìránṣẹ́ ni igba ti o wa ni Ile-ẹkọ gíga, owun àti àwọn ọrẹ rẹ ni wọ́n jọ béèrè rẹ. Eternity Network International(Eni) ni orúkọ ìṣe iranse rẹ, wọn dálè ni Oṣù Kẹta ni ọdún 2011, ní agboolé Zaria ni ìlú Kaduna ni Nigiria[1].Oti wàásù káàkiri àgbáyé pẹlu ìṣe àmì àti agbára.Ìṣe ìránṣẹ́ náà pín ẹka sì Ìlú Abuja ni Nàìjíríà, ní ọdún 2021.