Joslin Bipfubusa
Ìrísí
Joslin Sharif Bipfubusa (ti a bi ni ọjọ kewa Oṣu Kẹwa Ọdun 1984) jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede Burundi. Oun na ni alabojuto Burundi lọwọlọwọ.
Iṣẹ iṣakoso
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bipfubusa ṣakoso Burundi lakoko idije Bangabandhu 2020, ni atẹle ise adaṣe ti o ti ṣakoso Aigle Noir ati ẹgbẹ Burundi labẹ-20 .