Joyce Obehi Abdulmalik
Ìrísí
HON. Justice Joyce Obehi Abdulmalik jẹ́ Adájọ́ ní Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A bí i ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù keje ọdún 1968 ní London, ní ilẹ̀ United Kingdom. Ó jẹ́ ọmọ ìwọ̀-oòrùn Esan ní ìpínlẹ̀ Edo. [1]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "::::: Hon.Justice Joyce Obehi Abdulmalik, Federal High Court Nigeria :::::". ::::: Welcome to the Official Website of Federal High Court Nigeria :::::. 2015-12-01. Retrieved 2023-03-12.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]