Jump to content

Jumiat Ulama-e-Hind

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jamiat Ulema-e-Hind
Fáìlì:Jamiat Ulama-i-Hind logo.png
Ìdásílẹ̀Oṣù Kọkànlá 1919; ọdún 104 sẹ́yìn (1919-11)
TypeReligious organisation, NGO
Legal statusActive
Purpose/focusInitially to carry on non-violent freedom struggle against the British rule in India, its current purpose is the development of the Indian Muslim community
Ibùjókòó1, Bahadur Shah Zafar Marg, New Delhi
IbùdóITO
Region servedIndia
Ọmọẹgbẹ́Over 12 Million, and millions of followers.
PresidentÀdàkọ:Bulleted list
Website

Jamiat Ulema-e-Hindd tàbí Jamiat Ulama-i-Hind jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ẹgbẹ́ adarí Ọ̀mọ̀wé Mùsùlùmí [1] tí ó jẹ́ ti Deobandi Ilé-ìwé amòye ti Ìpìlẹ̀ rẹ̀ wáyé ní oṣù kọkànlá ọdún 1919 láti ọwọ́ ẹgbẹ́ Ọ̀mọ̀wé Mùsùlùmí pẹ̀lú Abdul Bari Firangi Mahali, Kifayatullah Dehlawi, Muhammad Ibrahim Mir Sialkoti àti Sanaullah Amritsari.

Jamiat jẹ́ ẹni tó ṣiṣẹ́ gidi ní Khilafat Movement pẹ̀lú ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú u Indian National Congress. Ó tún lòdì sí ìpín yà tí India, gbígba ipò ti composite nationalism: tí Mùsùlùmí àti aláìṣe-Mùsùlùmí dá orílẹ̀-èdè kan. Gẹ́gẹ́ bí èsì àbájáde, Ilé-iṣẹ́ yìí tú ká díè ní ìgbà náà tí a mọ̀ sí èka Jamiat Ulema-e-Islam, tí ó pinu láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Pakistan movement.

Ìwé òfin ti Jamiat di tí tẹ̀ jáde láti ọwọ́ ọ Kifayatullah Níhi. Ní 2021, ó tàn ká lẹ̀ àwọn Ìpínlẹ̀ ẹ India àti pé ó dá ilé-ẹ̀kọ́ àti ìyẹ́ bí i ti Idara Mabahith-e-Fiqhiyyah, 'Jamiat National Open School', Jamiat Ulama-e-Hind Halal Ìgbẹ́kẹ̀lé, padi olófìn ti Ilé ẹ̀kọ́ àti ti Jamiat kumo ẹgbẹ́ ọ̀dọ́. Arshad Madani ṣàṣeyọrí arákùnrin rẹ̀ Asad Madani gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ní oṣù kejì ọdún 2006, síbẹ̀ síbẹ̀ Ilé-iṣẹ́ pín sí í ẹgbẹ́ ẹ Arshad àti ẹgbẹ́ ẹ Mahmood ní oṣù kẹta ọdún 2008. Usman Mansoorpuri di Ààrẹ ti ẹgbẹ́ Mahmood, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní sin ipò náà títí ó fí kú ní oṣù karùn ọdún 2021. Mahmood Madani ṣàṣeyọrí lórí ẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ kí ó tó di yíyàn gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ ní ọjọ́ méjìdínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2021. Arshad Madani ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ ti ẹgbẹ́ ẹ Arshad.

  1. Khan, Feisal (2015). Islamic Banking in Pakistan: Shariah-Compliant Finance and the Quest to make Pakistan more Islamic. Routledge. p. 253. ISBN 978-1-317-36652-2. https://books.google.com/books?id=Z1pACwAAQBAJ&pg=PT253. Retrieved 25 January 2019.