Káyọ̀dé Ọlásẹ̀hìndé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Káyọ̀dé Ọlásẹ̀hìndé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Pa James ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù Kẹfà ọdún 1957 (4th June 1957)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ aláwàdà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúmọ̀ òṣèré nínú eré àwàdà tẹlifíṣàn tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Bàbá Ajasco. Kódà nínú eré yìí ni wọ́n ti sọ ó ní orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ Pa Jame. Káyọ̀dé Ọlásẹ̀yìndé ni bàbá Samuel Ọlásẹ̀yìndé, ọ̀dọ́mọdé òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan, ṣùgbọ́n tí ó ti dàgbà gẹ́gẹ́ bí òṣèré bákan náà. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Kayode Olasehinde Pa James: Biography - Filmography - Awards". Flixanda. 1957-06-04. Retrieved 2020-01-11. 
  2. Published (2015-12-15). "Dad is a no-nonsense person, he is only comical in movies – Pa James’ son". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-11.