Káyọ̀dé Odùmósù (Pa Kásúmù)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Káyọ̀dé Odùmósù tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Pa Kásúmù ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹta ọdún 1953 (16th March 1957) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti oǹkọ̀tàn sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Pa Kásúmù di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà nígbà tí ó kópa nínú àwọn sinimá-àgbéléwò, ṣàngó lọ́dún 1998, Jésù Muṣin lọ́dún 2002 àti Tales of Eve: Simi, 2011. Lẹ́yìn náà, ó ti kópa nínú ẹgbẹlẹmùkú sinimá àgbéléwò mìíràn.[1] [2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Published (2015-12-15). "Pa Kasumu gets new passport, at last". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-11. 
  2. "My Illness Was A Blessing In Disguise –Kayode Odumosu Aka Pa Kasunmu". Gistmania. Retrieved 2020-01-11. 
  3. "Actress launches lifeline for ailing, aged Nollywood actors". Premium Times Nigeria. 2019-12-03. Retrieved 2020-01-11.