Kafilat Ogbara
Ìrísí
Kafilat Ọ̀gbàrá | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria for Kosofe | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga June 2023 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1972 Lagos |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | APC |
Ẹbí | Alhaji & Alhaja M. Ade Kasumo |
Residence | Abuja |
Alma mater | University of Lagos |
Occupation |
|
Kafilat Ọ̀gbàrá jẹ́ oníṣòwò àti òṣèlú ọmọ ẹgbẹ́ aṣojú-ṣòfin ẹ̀kẹwàá ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria House of Representatives.[1][2] Ó borí nínú ìdìbò lọ́dún 2023 nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress pẹ̀lú iye ìbò 45,111, èyí ló fi borí àwọn alátakò rẹ̀, Florence Adepegba, tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic party tí ó rí iye ìbò tí ó jẹ́ 28,964 àti Abdulwaheed Odunuga ti ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria People's Party tí ó rí ìbò 4152.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ ((Editor)) (2022-05-27). "Ogbara Kafilat wins APC House of Rep ticket for Kosofe" (in en-US). The Guardian (Nigeria). https://guardian.ng/news/ogbara-kafilat-wins-apc-house-of-rep-ticket-for-kosofe/.
- ↑ Adeniran, Feranmi. "NASS leadership: Reps member-elect urges APC to be gender friendly". The Nation. https://thenationonlineng.net/nass-leadership-reps-member-elect-urges-apc-to-be-gender-friendly/.
- ↑ Abeyomi, Bilesanmi (2023-02-27). "Kosofe elect first female House of Representatives member" (in en-US). Kosofe Post. https://kosofepost.com/2023/02/27/kosofe-elect-first-female-house-of-representatives-member/.