Jump to content

Kajari melon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox cultivar Eso Kajari melon, je eso ti a tun mo si Delhi melon, o tun je irúgbìn ti ìsèdálè rẹ wà lati Punjab, a máan gbin nitori awọ re ti o yatọ .[1]

O won 2–3 pounds (0.91–1.36 kilograms)[1] ati rindi Tirin re je pupa sí awo osan pẹlu stripu alawọ ewe ,inu re je awo ewe ti o sunmọ honeydew.O ri roboto sí oblate ni awo. O le so ni asiko kekere ati wipe o le si USDA zones, titi to fi kàn zone 6. Flavour re sunmo honeydew sugbon o dun julo. A se afihan re United state ti ile Amerika ni ọdún 2014 nipasẹ Joseph Simcox ti o je botanical explorer.[1][2]

Eso irúgbìn yìí wa ni gbogbo ibi ni ayelujara.

  1. 1.0 1.1 1.2 "Kajari Melon". www.rareseeds.com. Archived from the original on 2021-10-19. Retrieved 2023-12-19. 
  2. Mattus, Matt (2016-08-31). "Back To School with Cucurbits" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-01-16. Retrieved 2021-01-14. 

Àdàkọ:Melons

Àdàkọ:Fruit-stub