Kalulu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kalulu
Kalulu in a suit
Ọjọ́ìbíNdugu M’Hali
c.1865
Africa
Aláìsí28 Oṣù Kẹta 1877
Kalulu Falls lẹ́bàá odò Lualaba
Cause of deathìrìlómi
Ẹ̀kọ́fún gbàdíẹ̀ ní Wandsworth

Ndugu M’Hali tabi Kalulu (c.1865 – 1877) je omo Afrika oniwofa ati omo agbatoju si Henry Morton Stanley. O ku nigba odo sugbon nigba igbesiaye soki re o se abewo lo si Europe, Amerika ati Seychelles. O je yiyesi pelu iwe kan, o je yiyalaworan ni Madame Tussauds bee sini o je alejo nigba isinku Dr Livingstone.[1]

Itan igbesiaye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

M’Hali je bibi ni Afrika o si di alayanfe Henry Morton Stanley leyin ti won fifun ni Tabora ni Tanzania. Stanley fun ni ominira o si yi oruko re si Kalulu. Oruko re tele ni "Ndugu M’Hali" to tumosi "Arakunrin ore mi".[1] Stanley pe ni Kalulu nitori pe o ro pe o tumoso ọmọ ẹtù sugbon awon miran ti so pe o je ehoro.

A studio picture of Kalulu and Stanley

Some see their relationship as homosexual but there is no firm evidence.[1] Leyin igba ti Stanley sawari Dr Livingstone o pada si Ilegeesi o si mu Kalulu pelu re.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 Colonialism and homosexuality p.43-44, Robert F. Aldrich, 2003, Routledge, accessed July 2010