Kànnà-n-gó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Kanna-n-go (Drum))
Jump to navigation Jump to search

Kanna-n-go (Drum)

Kànnàngó: -

Igi ti a fi se kànnàngó kéré jù igi ti a fi se ìsaaju. Ṣùgbọ́n gbogbo ohun ti ìsaájú ni náà ni kannango ni. Bì a ba tẹ kọ̀ngọ́ bọ kànnàngó, o n dun leti kerekere ju ìsaájú.