Kanpei
Kanpei, je eso ti a tun mo sí Ehime queen splash, a tun le pe ni irúgbìnCitrus ti o ṣẹ wá lati Japan.[1]
Genetics
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kanpei je eso ti a ṣẹda nipa didakoja dekopon ati oríṣi nishinokaori ni ọdún 1991,[1] nítòótó a se afihan re afi nigbati o di osu ogun ni ọdún 2007.[2]
Àpèjúwe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Igi yìí jé igi ti o se karakara ti o dé dagba dada titi ìwásè eso yìí. Egun ma'am Tobi ,a sì máa saaran sugbon o máa kere pẹlu ọjọ ori ati wipe awọn ẹka ti o nso eso yìí jé ailailegun. Eso yìí maan pon ni osu sere sí osu erena ,a tun maan ti iwọn 0.5pounds (230 grams) ati wipe irisi re je oblate. Rindi je awo osan ni colour ati wipe o ri runmurunmu lawo sugbon o ri bakan díẹ lára; eran are re je awo osan sí red orange. O maan tete sí ati wipe wiwu re sọwọn. A mo ni igi ti ko ni eso ninu amo nigbati awọn eso irúgbìn ti o wa layika ba pollinate re,o le ni eso diẹ ninu.O je eso ti o se dada,won a tun ma ni o ni oorun didun. Sugar content re to brix metala ati citric acid re to 1 percenti. Eso yìí máa tètè fo ni summer ati autumn.
Lilọ re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A máa ta pẹlu gbigbin re ni Japan, pàápàá jùlọ ni Ehin perfecture,a sì tún máa jẹ ni tutu. A sì máa je gẹgẹ bi dessert
O le wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn Atokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Shigematsu, Y. (Ehime-ken Fruit Tree Experiment Station; Kita, K.; Yakushiji, H.; Ishikawa, K.; Inoue, H.; Nakata, H. (2008). "The new citrus cultivar 'Kanpei'". Bulletin of Ehime Fruit Tree Experiment Station (Japan) (in Japanese). Retrieved 16 February 2021.
- ↑ "KM_654e-20180530112506" (PDF). aifood.jp. Retrieved 16 February 2021.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]