Kanta museum
Ìrísí
Mùsíọ́mu Kanta jẹ́ Mùsíọ́mu ní ìlú Argungu, ní orílẹ̀ èdè Nigeria, tó dẹ̀gbẹ́ kọjú sí ọjà.
Wọ́n kọọ́ ní ọdún 1831, wọ́n sì sọọ́ lórúkọ lẹ́yìn Muhammed Kanta, tí ó tẹ Kebbi Kingdom dó ní ọdún 1515. Tí Yakubu Nabame sì kọọ́, ọba Kebbi, tí ó sì jẹ títí di 1942 tí àwọn aláwọ̀ funfun fi kọ́ ààfin tuntun ní àkókò ìjọba Muhammed Sani. Lẹ́yìn tí ààfin náà ṣófo, ní ọdún 1958, wọ́n ṣíi gẹ́gẹ́ bíi mùsíọ́mù, tí ó ṣàlàyé àránbá tí ó jẹ́ baba ìtàn ti ìpínlẹ̀ Kebbi.
Mùsíọ́mù náà pín sí ìdá mọ́kànlá tí ó sì ní àwọn ohun irinṣẹ́ ogun, tí ó kún fún ògùn, ọ̀pọ̀ ìdàrọ, ọ̀pọ̀ idà,igi, ọ̀pọ̀ òkúta, ọ̀pọ̀ ọfà àti ọ̀pọ̀ àkọ̀, ìbọn àgbélẹ̀rọ àti bákan náà àwọn ìlù fún ìṣàfihàn.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Next Archived 2011-07-21 at the Wayback Machine.