Karin Barber

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Karin Barber

Oluko litireso ni Karin Barber je ni eka-eko Ede ati Litireso Aafirika fun ojo pipe. Eka-eko yii ni o ti n sise nigba ti o n kawe oye omowe re lori litireso. 1984 ni o fi eka-eko yii sile. Ni odun 2001 o gba Ẹ̀bùn Herskovits fun ise re, The Generation of Plays: Yoruba Popular Life in Theater.

  • Karin Barber (2000) Yorùbá dùn ún so, Ibadan; New Horn Press, ISBN 978-2266-32-9 Ojú-iwé 119.