Kate Raymond Mamuno
Ìrísí
Kate Raymond Mamuno jẹ́ olóṣèlú àti aṣofin ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹ bi adari ọmọ aṣòfin ti opó julọ ti Ile-igbimọ Aṣofin Ìpínlẹ̀ Adamawa ti o nsójú agbègbè Demsa ni ìpínlè Adamawa . [1] [2] [3]