Katherine Jackson
Appearance
Katherine Jackson | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kattie B. Screws 4 Oṣù Kàrún 1930 Clayton, Alabama, U.S. |
Iṣẹ́ | Author |
Olólùfẹ́ | Joe Jackson (m. 1949; died 2018) |
Àwọn ọmọ | 10 (incl. Michael, Janet; see below) |
Ẹbí | Jackson |
Katherine Esther Jackson (née Scruse, orúkọ àbísọ Kattie B. Screws; May 4, 1930) ni ìyá-àgbà ìdílé Jackson. Òhun ni ìyá Michael àti Janet Jackson àti àwọn ẹ̀gbọ́n wọn.