Kathryn Thornton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Kathryn Ryan Cordell Thornton
NASA Astronaut
Orílẹ̀-èdèAmerican
IpòRetired
ÌbíOṣù Kẹjọ 17, 1952 (1952-08-17) (ọmọ ọdún 68)
Montgomery, Alabama
Iṣẹ́ mírànPhysicist
Àkókò ní òfurufú40d 15h 14m
Ìṣàyàn1984 NASA Group
ÌránlọṣeSTS-33, STS-49, STS-61, STS-73
Àmìyẹ́sí ìránlọṣeSts-33-patch.pngSts-49-patch.pngSts-61-patch.pngSts-73-patch.png

Kathryn Ryan Cordell Thornton (Ph.D.) (ojoibi August 17, 1952 in Montgomery, Alabama) je onimosayensi ati arinlofurufu tele fun NASA ara Amerika to ti lo wakati 975 ni ofurufu. Lowolowo ohun ni Igbakeji Olori Eko fun awon Eto Iparieko ni Ile-Eko Iseero ati Sayensi Alamulo ti University of Virginia.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]