Jump to content

Kaycee Madu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kaycee Madu

Minister of Justice and Solicitor General of Alberta
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
August 25, 2020
PremierJason Kenney
AsíwájúDoug Schweitzer
Minister of Municipal Affairs of Alberta
In office
April 30, 2019 – August 25, 2020
PremierJason Kenney
AsíwájúShaye Anderson
Arọ́pòTracy Allard
Member of the Legislative Assembly of Alberta for Edmonton-South West
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
April 16, 2019
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíÀdàkọ:Birth based on age as of date[1]
Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Conservative Party
ResidenceEdmonton, Alberta
Occupationlawyer

Kaycee (Kelechi) Madu jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà [2][3] ṣùgbọ́n tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí amọ̀fin àti òṣèlú ní orílẹ̀ èdè Kánádà. Òun ni Mínísítà aṣẹ̀ṣẹ̀yàn Ìpínlẹ̀ Alberta ní orílẹ̀-èdè Kánádà. Wọ́n dìbò yàn-án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Alberta lọ́dún 2019, láti ṣojú ẹkùn ìdìbò electoral district.[4] Lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 2019,Wọ́n Madu sínú Ìgbìmọ̀ ìṣèjọba, Executive Council of Alberta gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò olú-ìlú náà. Ìpò yìí ló dìmú títí dọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2020 tí wọ́n tún fi yàn án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà ètò ìdájọ́ àti Amọ̀fin-àgbà ní Alberta lórílẹ̀-èdè Kánádà.

Pẹ̀lú àṣẹ láti òfin ìgbìmọ̀ iìṣèjọba, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Alberta fún Madu ni oyè Queen's Counsel lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2020. Oyè Queen's Counsel ni oyè tí ó ga jùlọ tí wọ́n máa ń fún àwọn aṣòfin tó bá dáńgájíá nípa ìdàgbàsókè òfin àti ìlú


Àdàkọ:Canadian cabinet member navigational box headerÀdàkọ:Ministry box cabinet postsÀdàkọ:S-end

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Paige Parsons (2019-04-10). "Alberta Election 2019 riding profile: Edmonton-South West". Edmonton Journal. Retrieved 2019-04-17. 
  2. "CLOSE-UP: Madu, Nigerian-born lawyer, appointed justice minister in Canadian province". TheCable. 2020-08-26. Retrieved 2020-08-27. 
  3. "Obi hails Kaycee Madu on new appointment". The Sun Nigeria. 2020-08-27. Retrieved 2020-08-27. 
  4. Derek Van Diest Updated: April 16, 2019. "Results: Kacyee Madu wins Edmonton-South West in tightly contested battleground". Edmonton Journal. Retrieved 2019-04-17.